ASE MAYE ...
Aanu ni Jabesi ri gba
Aanu ni Jobu ri gba
Aanu ni Obediodomu ri gba
Aanu ni Modekai ri gba
Aanu ni Josefu ri gba
Aanu ni Elisha ri gba
Aanu ni Batolomiu ri gba
Aanu ni omo Jairu ri gba
Aanu ni Lasaru ri gba
E gbo,lati oni yi lo E o ri aanu GBA nitori awon wonyi ri aanu gba,o di dandan Eyin naa yoo ri aanu gba lodun yi loruko Jesu..Fi adura yi ranse si awon ore re pelu ebi ee
Ase adura lowo maye...
Dr Ramon Adodoyin
Maye of Yoruba kingdom
Comments
Post a Comment